Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 32:35 BIBELI MIMỌ (BM)

Èmi OLUWA ni ẹlẹ́san, n óo sì gbẹ̀san,nítorí ọjọ́ ń bọ̀, tí àwọn pàápàá yóo yọ̀ ṣubú.Ọjọ́ ìdààmú wọn kù sí dẹ̀dẹ̀,ọjọ́ ìparun wọn sì ń bọ̀ kíákíá.

Ka pipe ipin Diutaronomi 32

Wo Diutaronomi 32:35 ni o tọ