Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 32:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹyọ ẹnìkan ṣoṣo ṣe lè lé ẹgbẹrun eniyan?Àní, eniyan meji péré ṣe lè lé ẹgbaarun eniyan sá?Bí kò bá jẹ́ pé Ọlọrun aláàbò wọn ti kọ̀ wọ́n sílẹ̀,tí OLUWA sì ti fi wọ́n lé àwọn ọ̀tá wọn lọ́wọ́.

Ka pipe ipin Diutaronomi 32

Wo Diutaronomi 32:30 ni o tọ