Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 32:24 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo fi ebi pa wọ́n ní àpakú,iná yóo jó wọn ní àjórun,n óo sì fi àjàkálẹ̀ àrùn pa wọ́n run.N óo jẹ́ kí àwọn ẹranko burúkú pa wọ́n jẹ,n óo sì jẹ́ kí àwọn ejò olóró bù wọ́n ṣán.

Ka pipe ipin Diutaronomi 32

Wo Diutaronomi 32:24 ni o tọ