Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 32:15 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ṣugbọn ẹ̀yin ọmọ Jeṣuruni, ẹ yó tán,ẹ wá tàpá sí àṣẹ;ẹ rí jẹ, ẹ rí mu, ẹ sì lókun lára;ẹ wá gbàgbé Ọlọrun tí ó da yín,ẹ sì ń pẹ̀gàn àpáta ìgbàlà yín!

Ka pipe ipin Diutaronomi 32

Wo Diutaronomi 32:15 ni o tọ