Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 32:13 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ó fi wọ́n jọba lórí àwọn òkè ayé,ó sì fún wọn ní èso ilẹ̀ jẹ.Ó pèsè oyin fún wọn láti inú àpáta,ó sì mú kí igi olifi hù fún wọn lórí ilẹ̀ olókùúta.

Ka pipe ipin Diutaronomi 32

Wo Diutaronomi 32:13 ni o tọ