Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 32:10 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ninu aṣálẹ̀ ni ó ti rí wọn,níbi tí kò sí igi tabi koríko, àfi kìkì yanrìn.Ó yí wọn ká, ó sì ń tọ́jú wọn,Ó sì dáàbò bò wọ́n bí ẹyin ojú rẹ̀.

Ka pipe ipin Diutaronomi 32

Wo Diutaronomi 32:10 ni o tọ