Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 31:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí mo mọ̀ dájú pé gẹ́rẹ́ tí mo bá kú tán, ìṣekúṣe ni ẹ óo máa ṣe, ẹ óo sì yipada kúrò ní ọ̀nà tí mo ti pa láṣẹ fun yín, ibi ni yóo sì ba yín ní ọjọ́ iwájú, nítorí pé ẹ óo ṣe ohun tí ó burú lójú OLUWA. Iṣẹ́ ọwọ́ yín yóo sì mú un bínú.”

Ka pipe ipin Diutaronomi 31

Wo Diutaronomi 31:29 ni o tọ