Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 31:16 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA tún sọ fún Mose pé, “Ọjọ́ àtisùn rẹ kù sí dẹ̀dẹ̀. Àwọn eniyan wọnyi yóo lọ máa bọ àwọn oriṣa tí àwọn ará ilẹ̀ náà ń bọ. Wọn óo kọ̀ mí sílẹ̀, wọn óo sì da majẹmu tí mo bá wọn dá.

Ka pipe ipin Diutaronomi 31

Wo Diutaronomi 31:16 ni o tọ