Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 30:9 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA Ọlọrun yín yóo bukun iṣẹ́ ọwọ́ yín lọpọlọpọ, ati àwọn ọmọ yín; àwọn ọmọ mààlúù yín, ati àwọn ohun ọ̀gbìn yín, nítorí inú OLUWA yóo tún dùn láti bukun yín gẹ́gẹ́ bí ó ti ṣe inú dídùn sí àwọn baba yín,

Ka pipe ipin Diutaronomi 30

Wo Diutaronomi 30:9 ni o tọ