Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 30:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn nítòsí yín ni ọ̀rọ̀ náà wà, ó wà lẹ́nu yín, ó sì wà ninu ọkàn yín, tí ó fi jẹ́ pé ẹ lè ṣe é.

Ka pipe ipin Diutaronomi 30

Wo Diutaronomi 30:14 ni o tọ