Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 30:1 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nígbà tí gbogbo àwọn ibukun tabi ègún tí mo gbé kalẹ̀ níwájú yín lónìí bá ṣẹ mọ́ yín lára, tí ẹ bá dé ààrin àwọn orílẹ̀-èdè tí OLUWA yóo fọn yín ká sí, tí ẹ bá ranti anfaani tí ẹ ti sọnù,

Ka pipe ipin Diutaronomi 30

Wo Diutaronomi 30:1 ni o tọ