Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 3:8 BIBELI MIMỌ (BM)

“A gba ilẹ̀ náà lọ́wọ́ àwọn ọba Amori mejeeji tí wọ́n wà ní òkè odò Jọdani nígbà náà. Ohun tí ó bẹ̀rẹ̀ láti àfonífojì Anoni títí dé òkè Herimoni.

Ka pipe ipin Diutaronomi 3

Wo Diutaronomi 3:8 ni o tọ