Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 3:4 BIBELI MIMỌ (BM)

A gba gbogbo àwọn ìlú ńláńlá rẹ̀ nígbà náà, kò sí ìlú kan tí a kò gbà lọ́wọ́ wọn ninu gbogbo àwọn ìlú wọn. Gbogbo ìlú wọn jẹ́ ọgọta, gbogbo agbègbè Arigobu ati ìjọba Ogu ní Baṣani ni a gbà.

Ka pipe ipin Diutaronomi 3

Wo Diutaronomi 3:4 ni o tọ