Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 3:24 BIBELI MIMỌ (BM)

‘OLUWA Ọlọrun, o ṣẹ̀ṣẹ̀ bẹ̀rẹ̀ sí fi títóbi ati agbára rẹ han èmi iranṣẹ rẹ ni; nítorí pé, oriṣa wo ló wà, lọ́run tabi láyé yìí tí ó lè ṣe àwọn iṣẹ́ ìyanu bíi tìrẹ?

Ka pipe ipin Diutaronomi 3

Wo Diutaronomi 3:24 ni o tọ