Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 3:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn OLUWA wí fún mi pé, ‘Má bẹ̀rù rẹ̀, nítorí pé mo ti fi òun ati àwọn eniyan rẹ̀ ati ilẹ̀ rẹ̀ lé ọ lọ́wọ́, ohun tí o ṣe sí Sihoni, ọba àwọn ará Amori, tí ń gbé Heṣiboni ni kí o ṣe sí òun náà.’

Ka pipe ipin Diutaronomi 3

Wo Diutaronomi 3:2 ni o tọ