Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 3:18 BIBELI MIMỌ (BM)

“Mo pàṣẹ fun yín nígbà náà, mo ní, ‘OLUWA Ọlọrun yín ti fi ilẹ̀ yìí fun yín bíi ohun ìní; gbogbo àwọn akọni ninu àwọn ọkunrin yín yóo kọjá lọ pẹlu ihamọra ogun ṣiwaju àwọn ọmọ Israẹli, arakunrin yín.

Ka pipe ipin Diutaronomi 3

Wo Diutaronomi 3:18 ni o tọ