Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 3:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ Reubẹni ati àwọn ọmọ Gadi ni mo sì fún ní agbègbè Gileadi títí dé àfonífojì Anoni, ààrin gbùngbùn àfonífojì náà ni ààlà ilẹ̀ wọn, títí lọ kan odò Jaboku, tíí ṣe ààlà àwọn ará Amoni;

Ka pipe ipin Diutaronomi 3

Wo Diutaronomi 3:16 ni o tọ