Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 29:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí irú ẹni tí ń gbọ́ ọ̀rọ̀ majẹmu má baà dá ara rẹ̀ lọ́kàn le pé ‘Kò séwu, bí mo bá fẹ́ mo lè ṣe orí kunkun kí n sì máa tẹ̀lé ìmọ̀ ara mi.’ Èyí yóo kó ìparun bá gbogbo yín, ati àwọn tí wọn ń ṣe ibi ati àwọn tí wọn ń ṣe rere.

Ka pipe ipin Diutaronomi 29

Wo Diutaronomi 29:19 ni o tọ