Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 28:53 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ojú yóo pọn yín tóbẹ́ẹ̀ gẹ́ẹ́, nígbà tí àwọn ọ̀tá yin bá dó tì yín, tí yóo fi jẹ́ pé àwọn ọmọ yín lọkunrin ati lobinrin, tí OLUWA Ọlọrun yín fun yín, ni ẹ óo máa pa jẹ.

Ka pipe ipin Diutaronomi 28

Wo Diutaronomi 28:53 ni o tọ