Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 28:45 BIBELI MIMỌ (BM)

“Gbogbo ègún wọnyi ni yóo ṣẹ si yín lára, tí yóo sì lẹ̀ mọ́ yín pẹ́kípẹ́kí títí tí ẹ óo fi parun, nítorí pé ẹ kò gbọ́ ti OLUWA Ọlọrun yín, ẹ kò pa òfin rẹ̀ mọ́, ẹ kò sì tẹ̀lé àwọn ìlànà tí ó pa láṣẹ fun yín.

Ka pipe ipin Diutaronomi 28

Wo Diutaronomi 28:45 ni o tọ