Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 28:35 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA yóo da oówo burúkú bò yín lẹ́sẹ̀ ati lórúnkún, yóo burú tóbẹ́ẹ̀ tí ẹnikẹ́ni kò ní lè wò yín sàn. Láti àtẹ́lẹsẹ̀ yín títí dé àtàrí yín kìkì oówo ni yóo jẹ́.

Ka pipe ipin Diutaronomi 28

Wo Diutaronomi 28:35 ni o tọ