Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 28:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọn óo máa pa akọ mààlúù rẹ lójú rẹ, o kò ní fẹnu kàn ninu rẹ̀. Wọn óo fi tipátipá mú kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ rẹ lọ lójú rẹ, wọn kò sì ní dá a pada fún ọ mọ́. Àwọn aguntan yín yóo di ti àwọn ọ̀tá yín, kò sì ní sí ẹni tí yóo ràn yín lọ́wọ́.

Ka pipe ipin Diutaronomi 28

Wo Diutaronomi 28:31 ni o tọ