Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 28:29 BIBELI MIMỌ (BM)

O óo máa táràrà lọ́sàn-án gangan bí afọ́jú. Kò ní dára fún ọ ní gbogbo ọ̀nà rẹ. Wọn yóo máa ni ọ́ lára, wọn yóo sì máa jà ọ́ lólè nígbà gbogbo; kò sì ní sí ẹnìkan láti ràn ọ́ lọ́wọ́.

Ka pipe ipin Diutaronomi 28

Wo Diutaronomi 28:29 ni o tọ