Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 28:27 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA yóo da irú oówo tí ó fi bá àwọn ará Ijipti jà bò ọ́, ati egbò, èkúkú ati ẹ̀yi, tí ẹnikẹ́ni kò ní lè wòsàn.

Ka pipe ipin Diutaronomi 28

Wo Diutaronomi 28:27 ni o tọ