Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 27:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Mose ati àwọn alufaa, ọmọ Lefi, bá wí fún gbogbo ọmọ Israẹli pé, “Ẹ dákẹ́ jẹ́ẹ́, kí ẹ sì gbọ́, ẹ̀yin ọmọ Israẹli, òní ni ẹ di eniyan OLUWA Ọlọrun yín.

Ka pipe ipin Diutaronomi 27

Wo Diutaronomi 27:9 ni o tọ