Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 27:22 BIBELI MIMỌ (BM)

“ ‘Ẹni ìfibú ni ẹnikẹ́ni tí ó bá bá arabinrin rẹ̀ lòpọ̀, kì báà jẹ́ ọmọ ìyá rẹ̀ tabi ọmọ baba rẹ̀.’“Gbogbo eniyan yóo sì dáhùn pé, ‘Amin.’

Ka pipe ipin Diutaronomi 27

Wo Diutaronomi 27:22 ni o tọ