Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 26:17 BIBELI MIMỌ (BM)

O ti fi ẹnu ara rẹ sọ lónìí pé, OLUWA ni Ọlọrun rẹ, ati pé o óo máa rìn ní ọ̀nà rẹ̀, o óo máa pa gbogbo ìlànà ati òfin ati ìdájọ́ rẹ̀ mọ́, o óo sì máa gbọ́ tirẹ̀.

Ka pipe ipin Diutaronomi 26

Wo Diutaronomi 26:17 ni o tọ