Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 26:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Bojúwo ilẹ̀ láti ibùgbé mímọ́ rẹ lọ́run, kí o sì bukun Israẹli, àwọn eniyan rẹ, ati ilẹ̀ tí o ti fi fún wa gẹ́gẹ́ bí o ti ṣèlérí fún àwọn baba wa, ilẹ̀ tí ó kún fún wàrà ati oyin.’

Ka pipe ipin Diutaronomi 26

Wo Diutaronomi 26:15 ni o tọ