Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 25:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, obinrin náà yóo tọ̀ ọ́ lọ lójú gbogbo àwọn àgbààgbà, yóo bọ́ bàtà ẹsẹ̀ rẹ̀, yóo tutọ́ sí i lójú, yóo sì wí pé, ‘Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n ṣe sí ẹni tí ó bá kọ̀ láti kọ́ ilé arakunrin rẹ̀.’

Ka pipe ipin Diutaronomi 25

Wo Diutaronomi 25:9 ni o tọ