Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 25:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà nígbà tí OLUWA Ọlọrun yín bá fun yín ní ìṣẹ́gun lórí gbogbo àwọn ọ̀tá yín tí wọ́n wà ní àyíká yín, ní ilẹ̀ tí OLUWA Ọlọrun yín fun yín, pípa ni kí ẹ pa àwọn ará Amaleki run lórí ilẹ̀ ayé. Ẹ kò gbọdọ̀ gbàgbé.

Ka pipe ipin Diutaronomi 25

Wo Diutaronomi 25:19 ni o tọ