Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 24:1 BIBELI MIMỌ (BM)

“Bí ọkunrin kan bá fẹ́ iyawo, tí iyawo náà kò bá wù ú mọ́ nítorí pé ó rí ohun àléébù kan ninu ìwà rẹ̀ tí kò tẹ́ ẹ lọ́rùn; tí ó bá já ìwé ìkọ̀sílẹ̀ fún un, tí obinrin náà jáde kúrò ní ilé rẹ̀, tí obinrin náà sì bá tirẹ̀ lọ;

Ka pipe ipin Diutaronomi 24

Wo Diutaronomi 24:1 ni o tọ