Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 23:7 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ẹ kò gbọdọ̀ kórìíra àwọn ọmọ Edomu, nítorí pé arakunrin yín ni wọ́n. Ẹ kò gbọdọ̀ kórìíra àwọn ará Ijipti nítorí pé ẹ ti ṣe àtìpó ní ilẹ̀ wọn rí.

Ka pipe ipin Diutaronomi 23

Wo Diutaronomi 23:7 ni o tọ