Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 23:4 BIBELI MIMỌ (BM)

nítorí pé, nígbà tí ẹ̀ ń bọ̀ láti ilẹ̀ Ijipti, wọn kò gbé oúnjẹ ati omi pàdé yín. Kàkà bẹ́ẹ̀, Balaamu ọmọ Beori ará Petori, ní Mesopotamia, ni wọ́n bẹ̀ pé kí ó wá gbé yín ṣépè.

Ka pipe ipin Diutaronomi 23

Wo Diutaronomi 23:4 ni o tọ