Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 23:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ọkunrin kan bá wà ninu yín tí ó di aláìmọ́ nítorí ohun tí ó ṣẹlẹ̀ sí i láàrin òru, kí irú ẹni bẹ́ẹ̀ jáde kúrò ninu àgọ́. Kò gbọdọ̀ wọ inú àgọ́ wá mọ́.

Ka pipe ipin Diutaronomi 23

Wo Diutaronomi 23:10 ni o tọ