Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 22:8 BIBELI MIMỌ (BM)

“Tí ẹ bá kọ́ ilé titun, ẹ níláti ṣe ìgbátí sí òrùlé rẹ̀ yípo, kí ẹ má baà wá di ẹlẹ́bi bí ẹnikẹ́ni bá jábọ́ láti orí òrùlé yín, tí ó sì kú.

Ka pipe ipin Diutaronomi 22

Wo Diutaronomi 22:8 ni o tọ