Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 22:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé, inú igbó ni ó ti kì í mọ́lẹ̀. Bí ọmọbinrin àfẹ́sọ́nà yìí tilẹ̀ ké: ‘Gbà mí! Gbà mí!’ Kò sí ẹnikẹ́ni nítòsí tí ó lè gbà á sílẹ̀.

Ka pipe ipin Diutaronomi 22

Wo Diutaronomi 22:27 ni o tọ