Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 22:25 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ṣugbọn bí ó bá jẹ́ pé ninu igbó ni ọkunrin kan ti ki ọmọbinrin kan tí ó jẹ́ àfẹ́sọ́nà ẹnìkan mọ́lẹ̀, tí ó sì bá a lòpọ̀, ọkunrin nìkan ni kí wọ́n pa.

Ka pipe ipin Diutaronomi 22

Wo Diutaronomi 22:25 ni o tọ