Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 22:22 BIBELI MIMỌ (BM)

“Bí ọwọ́ bá tẹ ọkunrin kan ní ibi tí ó ti ń bá iyawo oníyàwó lòpọ̀, pípa ni ẹ gbọdọ̀ pa àwọn mejeeji; ati ọkunrin ati obinrin náà. Bẹ́ẹ̀ ni ẹ óo ṣe mú ibi yìí kúrò láàrin yín.

Ka pipe ipin Diutaronomi 22

Wo Diutaronomi 22:22 ni o tọ