Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 22:15 BIBELI MIMỌ (BM)

“Kí baba ati ìyá ọmọbinrin yìí mú aṣọ ìbálé rẹ̀ jáde, kí wọ́n sì mú un tọ àwọn àgbààgbà ìlú náà lọ ní ẹnubodè.

Ka pipe ipin Diutaronomi 22

Wo Diutaronomi 22:15 ni o tọ