Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 21:8 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA, dáríjì Israẹli, àwọn eniyan rẹ, tí o ti rà pada, má sì ṣe jẹ àwọn eniyan Israẹli níyà nítorí ikú aláìṣẹ̀ yìí. Ṣugbọn dárí ẹ̀bi ẹ̀ṣẹ̀ ìtàjẹ̀sílẹ̀ náà jì wọ́n.’

Ka pipe ipin Diutaronomi 21

Wo Diutaronomi 21:8 ni o tọ