Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 21:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí àwọn alufaa, àwọn ọmọ Lefi, bá wọn lọ pẹlu; nítorí àwọn ni OLUWA Ọlọrun yín yàn láti máa ṣe alufaa ati láti máa súre fún àwọn eniyan ní orúkọ OLUWA; ati pé àwọn ni OLUWA Ọlọrun yàn láti parí àríyànjiyàn ati ẹjọ́.

Ka pipe ipin Diutaronomi 21

Wo Diutaronomi 21:5 ni o tọ