Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 20:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ǹjẹ́ ọkunrin kan wà ninu yín tí ó ṣẹ̀ṣẹ̀ gbin ọgbà àjàrà, tí kò sì tíì jẹ ninu èso rẹ̀? Kí irú ẹni bẹ́ẹ̀ pada sí ilé rẹ̀, kí ó má baà jẹ́ pé bí ó bá kú sí ogun, ẹlòmíràn ni yóo jẹ èso ọgbà àjàrà rẹ̀.

Ka pipe ipin Diutaronomi 20

Wo Diutaronomi 20:6 ni o tọ