Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 20:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Rírun ni kí ẹ run gbogbo wọn patapata, gbogbo àwọn ará Hiti, ati àwọn ará Amori, ati àwọn ará Kenaani, ati àwọn ará Perisi, ati àwọn ará Hifi, ati àwọn ará Jebusi; gẹ́gẹ́ bí OLUWA Ọlọrun yín ti pa á láṣẹ.

Ka pipe ipin Diutaronomi 20

Wo Diutaronomi 20:17 ni o tọ