Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 20:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn kí ẹ dá àwọn obinrin ati àwọn ọmọ wọn sí, ati àwọn ẹran ọ̀sìn wọn, ati gbogbo dúkìá yòókù tí ó wà ninu ìlú náà, kí ẹ kó gbogbo rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ìkógun fún ara yín, kí ẹ máa lo gbogbo dúkìá àwọn ọ̀tá yín tí OLUWA Ọlọrun yín ti fun yín.

Ka pipe ipin Diutaronomi 20

Wo Diutaronomi 20:14 ni o tọ