Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 2:9 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA sọ fún mi pé, ‘Ẹ kò gbọdọ̀ da àwọn ará Moabu láàmú, tabi kí ẹ gbógun tì wọ́n; nítorí pé n kò fun yín ní ilẹ̀ wọn, nítorí pé mo ti fi ilẹ̀ Ari fún àwọn ọmọ Lọti gẹ́gẹ́ bí ohun ìní wọn.’ ”

Ka pipe ipin Diutaronomi 2

Wo Diutaronomi 2:9 ni o tọ