Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 2:30 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ṣugbọn Sihoni, ọba Heṣiboni kọ̀ fún wa, kò jẹ́ kí á kọjá lọ́dọ̀ rẹ̀; nítorí OLUWA Ọlọrun yín mú kí ọkàn rẹ̀ le, ó sì mú kí ó ṣe oríkunkun, kí ó lè fi le yín lọ́wọ́, bí ó ti ṣe lónìí.

Ka pipe ipin Diutaronomi 2

Wo Diutaronomi 2:30 ni o tọ