Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 2:24 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ẹ dìde, ẹ bẹ̀rẹ̀ ìrìn àjò yín, kí ẹ sì ré àfonífojì Anoni kọjá. Mo ti fi Sihoni, ọba Heṣiboni, ní ilẹ̀ àwọn ará Amori, le yín lọ́wọ́, àtòun ati ilẹ̀ rẹ̀. Ẹ bẹ̀rẹ̀ sí bá a jagun, kí ẹ sì máa gba ilẹ̀ rẹ̀.

Ka pipe ipin Diutaronomi 2

Wo Diutaronomi 2:24 ni o tọ