Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 2:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Gẹ́gẹ́ bí OLUWA ti ṣe fún àwọn ọmọ Esau tí wọn ń gbé òkè Seiri nígbà tí ó pa àwọn ará Hori run fún wọn, tí àwọn ọmọ Esau gba ilẹ̀ wọn, tí wọ́n sì tẹ̀dó sibẹ títí di òní olónìí, ni ó ṣe fún àwọn ará Amoni.

Ka pipe ipin Diutaronomi 2

Wo Diutaronomi 2:22 ni o tọ