Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 2:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. “Nígbà tí ó yá, a pada sinu aṣálẹ̀ ní ọ̀nà Òkun Pupa, gẹ́gẹ́ bí OLUWA ti pa á láṣẹ fún mi; a sì rìn káàkiri lórí òkè Seiri fún ọpọlọpọ ọjọ́.

2. “OLUWA bá wí fún mi pé,

Ka pipe ipin Diutaronomi 2