Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 18:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí ninu gbogbo ẹ̀yà Israẹli, ẹ̀yà Lefi ati ti arọmọdọmọ wọn ni OLUWA Ọlọrun yín ti yàn láti máa ṣe iṣẹ́ alufaa fún un.

Ka pipe ipin Diutaronomi 18

Wo Diutaronomi 18:5 ni o tọ